ln k Bibeli Fn gb DNILJ KR WN NY ...
ln k Bibeli Fn gb DNILJ KR WN NY ...
ln k Bibeli Fn gb DNILJ KR WN NY ...
You also want an ePaper? Increase the reach of your titles
YUMPU automatically turns print PDFs into web optimized ePapers that Google loves.
ln k Bibeli

Fn gb

DNILJ KR WN NYN MM

Efesu 2:1-6; Matteu 13:24-30; 1Tssalonika 4:13-17; 1Krinti 15:20-23, 35-38, 42-44, 50-

58.

ksr: “Awn ok ninu Kristi ni yio si k jinde: Nigbana li a si gb awa ti o w lye ti o si

k lhin soke plu wn sinu awsanma, lati pade Oluwa li oju run” (1Tssalonika 4:16,17).

r j

Peteru Apsteli s fn wa nipa imisi mi Mim p a tn wa bi “sinu ireti ye nipa ajinde Jesu

Kristi kuro ninu ok” (1Peteru 1:3). O si tn pe ogn wa ni ogn “aidibaj, ati ailabawn, ati eyi

ti ki i, ti a ti fi pam ni run” d w. Nipa imisi mi Mim, Paulu Apsteli tn s fn wa plu

nipa ireti Onigbagb, ati p ajinde Kristi ati ajinde awn eniyan mim ti yoo tle e, ni ipil ati

agbara ireti naa.

Ay ki b ti si bi o b e p ajinde k k si. Ki ba ti si ijsin, igbagb tabi awn m ti n tle

iwaasu r lrun; ki ba ti si igbala kuro ninu , tabi iwnum kuro ninu aidibaj ti d ub

si, bi o ba e pe ajinde k si. Igbagb wa i ba j asn awa i b w ninu wa sib. Nitori naa,

j ki a y otit ati ogo ti o w ninu ajinde ati ipalarada Ij lrun w, nitori ni ipadab Kristi ni

keji ni Ij Ajagun yoo di Ij Agun.

Awn alatako ti s agbara lrun ati otit r lrun a maa s otit ologo yii plu. ugbn

otit yii duro inin – Apata ti ireti Onigbagb duro l lori – ani p ajinde wa, ninu eyi ti Oluwa

ati Olugbala wa jade kuro ninu iboji ti si goke re run lati j Alagbawi wa. Ati nitori ti

gun ik ati ipo k, awa plu yoo jinde lati pade R ni awsanma nigbooe.

Awn ti o ti l aaju, ti k wn wa ninu iboji yoo j dide. Awn ti si wa laaye ni a pa lara

da, a si gb wn soke plu awn eniyan mim ti ti jinde. Gbogbo awn wnyi, plu k

awn olt ti a ti ji dide lyin Ipnju Nla, yoo j awn m-gb Ajinde Kin-in-ni, eyi ti

Kristi i e kso r. A le pe awa ti a pa lara da lati pade R ni akoko Ipalarada ni ikore gidi,

awn wnni ti a ji dide lyin Ipnju Nla ni a le p ni e ikore (1Krinti 15;20-23;

1Tssalonika 4:13-18).

Wo bi yoo ti dn t lati ni ipin ninu Ajinde Kin-in-ni! Ara wnyi ti o ti m oriirii aisan ati

ailera yoo di ara ologo. Gbogbo irora yoo dopin. Gbogbo ailera ati ijatil da ki yoo si m. Awa

yoo da bii Kristi, nitori awa yoo ri I gg bi Oun ti ri. I iwnum yii ti brsi i e ninu kn

awn eniyan lrun. Wn n mura sil fn j ni nigba ti Oun yoo pe wn. ugbn ni j ologo

ni Oun yoo e w ni ep, yoo si mu wa ri bi Oun tikara R ti ri.

gbs 1a. Awn wo ni Eniyan Mim lrun Awn Eniyan Mim lrun ni awn ti wn ti ri

igbala, isdimim ati ifiwni mi Mim ati in, ti wn si n gbe igbesi-aye Onigbagb

laiys. Efesu 2:19; 1Johannu 3:9; Johannu 3:3-7; Heberu 13:12; Ie Awn Apsteli 2:1-

4, 39.

b. Bawo ni a e s l di aaye lati di eniyan mim Efesu 2:1; Kolosse 2:13, 14;

Johannu 5:21, 24, 25.

gbs 2. Awn wo ni Jesu tka si bii “Alikama ati po” ninu Owe R Nj yst yoo wa

Matteu 13:24-30; 1Johannu 3:2, 3; Matteu 25:1-13; 24:40, 41; Luku 16:19-31; Danili 12:2.

gbs 3. Awn anfaani wo ni yoo j ti awn eniyan mim ni ay nihin

(i) Igbesi-ay tun: Efesu 5:8-11; Kolosse 1:13, 14; 2Krinti 5:17.

(ii) Aabo lrun: Orin Dafidi 91:1-7; 46:1; Owe 18:10.

(iii) ps lrun: Jobu 22:21; Filippi 4:19; Orin Dafidi 23:1.

1
(iv) tni lrun: Isaiah 30:21; Johannu 14:26; 16:13.

(v) Iwosan nipa Agbara lrun: Isaiah 53:5; Jakbu 5:14-16; 1Peteru 2:24.

(vi) Idahun s dr: Jobu 22:23, 27-29; Matteu 7:7-11; Johannu 15:7; 1Johannu 5:4, 5.

gbs 4. Ki ni e ti Ajinde Kristi fi e pataki fn wa e pataki fn wa nitori:

(i) j r p wn k yoo jinde: 1Krinti 15:12-20, 52;1Tssalonika 4:16.

(ii) j pl igbagb wa: 1Krinti 15:16, 17; Romu 4:25; 10:9.

(iii) j ireti ayeraye wa: 1Johannu 3:2, 3; 1Tssalonika 4:14-18; 1Peteru 1:3, 4.

gbs 5. S bi ajinde yoo ti r lss. Bayii ni yoo r;

(i) Kristi kb ninu awn oku. 1Krinti 15:20-22; Eksodu 22:29; Lefitiku 23:10; Ie Awn

Apsteli 26:23.

(ii) Awn k ninu Kristi. 1Tssalonika 4:16.

(iii) Awn eniyan mim lakoko Ipalarada. 1Krinti 15:51, 52; 1Tssalonika 4:17.

(iv) Awn mim ti akoko Ipnju Nla. Nigba wo Ni igba Ijba gbrun dun. Ifihan 20:4.

(v) Awn eniyan buburu. Ifihan 20:12-15.

gbs 6a. Ki ni o n duro de awn Onigbagb lyn ik Danili 12;2, 3; 1Tssalonika 4:16;

Ifihan 21:3-7.

b. Ki ni o duro de l lyin ik Danili 12:2; Ifihan 20:12-15; 21:8.

gbs 7. Ki ni ohun ti o e pataki j l fn wa lati e A gbd ni awn iriri Onigbagb

mtta, ki a si maa gb igbesi-ay Onigbagb laiys, ki a si maa i fn Oluwa.

Johannu 3:3-7; Heberu 13:12; Ie Awn Apsteli 2:1-4, 39; Matteu 25:14-23; Romu

12:6-11; Galatia 6:9; Danili 12:3.

Ikadii r

p ikyin yoo dn ni j kan ati p n ohn p naa, ara awn olododo ti wn ti k yoo jade kuro

ninu is-k wn, a si pa awn eniyan mim ti wn wa laaye lara da sinu ara ologo ti ki i k

(1Krinti 15:52, 53).

Awn kunrin, awn obinrin, awn dmkunrin ati dmbinrin ti a ti gbl, sdimim,ti a si

ti fi mi Mim ati in w ni toot, ti wn si n gb igbesi-ay ti o wu lrun n foju sn plu ay

si gb ti Jesu yoo d. K gbd si r ninu kan awn ti wn ti mura tan lati “pade Oluwa ni oju

run” ati plu awn eniyan mim ti wn ti jinde kuro ninu is k yoo maa wa “titi lai ld

Oluwa” (1Tssalonika 4:17). Bi Jesu b fa bb R syin, bi awn ti wn wa laaye lonii b til l

sinu is k, r yii paapaa k m fy b awn agun, nitori ik ti s “or” r n. Wn yoo ji

dide ni j ajinde. Bi a b ji, tabi bi a ba sn, ki a le jm w laaye plu r (1Tssalonika 5:10).

Ireti ologo ti n fa kn srun!

PNJ: NJ IW N RT YII

2