09.08.2015 Views

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

SHOW MORE
SHOW LESS

Create successful ePaper yourself

Turn your PDF publications into a flip-book with our unique Google optimized e-Paper software.

awon omo Ajo Igbimo laarin awon Ekun yato si awon ijoko ni ilu okeere ni won yoo pin n idogba dogba bi ati ko sile ni abala oke nipa lilo iye eniyan to ngbe ilu ti eeto ikaniyangbogbo gbo ti won se keyin.Atiku. 58Awon omo Ajo Igbimo ni awon agbalagba to to omo odun meedogbo maa ndibo yan taara.Awon oludibo to to omo ogoji odun lo leto lati dije fun ipo omo Ajo igbimo.Atiku. 59Awon to ti je Aare orileede ri je omo Ajo Igbimo fun gbogbo ojo aye won gege bi eto afi tiwon ba ko ipo na sile.Aare orileede lee yan omo ilu marun ti won ti pon orileede le nipa aseyori to wuni lori nipaigbayegbadun, imo sayensi, isenona ati nipa iwe kiko gege bi omo Ajo Igbimo fun gbogboojo aye won.Atiku. 60Ibujoko awon Asoju ati Ajo igbimo ti orileede olominira ni won maa ndibo si fun odunmarun. Saa fun okokan awon ile asofin naa ko gbodo je sisun siwaju ayafi labe ofin eyi ti osi je ni asiko ogun nikan.Idibo titun si awon Ile Asofin gbodo waye laarin aadorin ojo leyin ti saa awon ile asofin tokoja ba ti pari. Ipade akoko ni o gbodo je pipe laarin ogun ojo leyin idibo.Titi di asiko ti Awon ile asofin titun yoo fi se ipade, agbara ile igbimo asofin to nkoja lo yooma di sisun siwaju.Atiku. 62Awon ile Igbimo asofin le se ipade gege bi eti won ni ojo ise akoko ni osu keji ati osu kewa.Ile Igbimo asofin kookan le pe ipede ara oto nipase Aare ile igbimo asofin naa tabi nipaseAare orileede olominira tabi nipase idakan ninu meta awon omo ile asofin naa.Nigbati ile igbimo asofin kan ba nse ipade ara oto, ile igbimo asofin keji naa yoo se ipadetiwon gege bi eto.Atiku. 63Ile Igbimo Asofun kookan gbodo yan Aare ati awon oloye yoku laarin awon omo ile.Nigbati awon ile igbo o aosfin mejeeji ba se ipade apapo, Aare ati awon oloye ile igbimoasoin asoju ni yoo dari ile.Atiku. 64Ile Igbimo Asofin kookan le e se agbekale awon ilana a ntele eyi awon omo ile to poju yoofowosi. Ijoko awon ile gbodo je ni oju gbangba,sugbon ile kookan tabi apapo ile asofinmejeeji lee pinu lati se ipade bonkele. Ipinnu ile kookan tabi apapo awon ile asofin mejeejiko le je mimuse ti awon omo ile topoju koba si ninu ipade ati bi awon omo topuju laarinawon to wa nibi ipade naa ko fowosi ipinu naa ayafi tin ofin ba se ilasile akanse iye awonasofin to gbogbdo fowosi iru ipinnu bee.

Hooray! Your file is uploaded and ready to be published.

Saved successfully!

Ooh no, something went wrong!