09.08.2015 Views

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

SHOW MORE
SHOW LESS

Create successful ePaper yourself

Turn your PDF publications into a flip-book with our unique Google optimized e-Paper software.

Won le se igbekale ilana ofin , won si lee lowosi ikosile ilana ofin fun eeto oro aje ati igbeaye gbadun nipase ati labe gbedeke ti ofin la sile.Atiku 100Igbimo fun orileede je ajo nipa idajo ati isakoso ti o nsamojuto bi idajo ododo ninu iseisejoba. Awon aye iwe owo wo nse ojuse idalekun lati ri pe awon eeto ijoba ba ofin mu atilati maa ye iwe isuna bi ijoba se se akoso wo leyi o reyin. Won maa ndasi, lasiko ati lona tiofin la sile, iyewe owo isakoso awon agbekale ijoba to ngba owo loore koore lowo ijobanipase isuna.Won maa njabo taara fun awon Ile Asofin, ayorisi iwe owo ti won yewo.Ofin ri pe won ni ominira lowo awon eka ijoba mejeeji ati awon to nsakoso ijoba naa.AKOLE KARUNEKA IDAJOAbala kinniIsakoso Eeto idajoAtiku. 101Idajo ododo sise ni a ngbe kale loruko awon eniyan. Awon Adajo nbowofun ofin nikan.Atiku. 102Eeto idajo ni awon Adajo Majisitireti nse gege bi ofin idajo se gbe kale ati agbara ti ofinidajo fun won.A le maa se igbekale awon Adajo pataki. Awon abala kan to se pataki funawon koko pataki ni won lee gbe awon Onidajo pataki kale fun, iru igbekale yi lee ni awonomo ilu ti won kun oju osunwon sugbon ti won ki i se ara ajo to wa fun idajo ninu.Ofin lo nse idari awon asiko ati igba ti awon eniyan ilu le e kopa taara ninu ise eeto idajo.Atiku. 103Ajo Ilu ati awon eka ijoba eeto Idajo lo ni agbara ati ase lati dabo bo awon eeto ti won baofin mu nigbati isakoso ilu ba nlo, ati lori awon asiko to se koko ti ofin gbe kale.Eeto idajo awon omo Ologun ni asiko ogun ni ase ati agbara ti ofin la sile. Ni asiko alafiawon ni ase ati agbara lori iwa odaran to sele lati owo awon omo ologun nikan.Atiku. 104Eka to wa fun eeto Idajo je eka to da duro ti o si ni ominira lati owo gbogbo agbara to ku.Igbimo giga fun Eeto Idajo ni Aare Orileede olominira maa ndari.Olori akoko ati Oludari eka to maa ngbe Odaran lo si ile ejo je omo igbimo giga yi gege bieto.Idameji ninu meta omo igbimo giga yi ni awon Adajo lasan ti won wa lati orisirisi ipele maandibo yan, idakan to ku ni awon Asofin ni asiko Ipade asepo Ile mejeeji maa ndibo yanlaarin awon Ojogbo to nse oluko ni yunifasiti ati awon Agbejoro ti won ti ngbejoro fun odunmeedogun.Gbimo naa maa nyan igbakeji olori laarin awon omo igbimo ti awon asofin dibo yan.

Hooray! Your file is uploaded and ready to be published.

Saved successfully!

Ooh no, something went wrong!