09.08.2015 Views

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

SHOW MORE
SHOW LESS

Create successful ePaper yourself

Turn your PDF publications into a flip-book with our unique Google optimized e-Paper software.

Atiku. 21Gbogbo eniyan lo leto lati so ero okan won jade, nipa siso jade, kiko sile tabi gbogboorisirisi ona ibara eni soro. A ko gbodo maa pase tabi se ayewo Awon ohun ti awononiroyin lee ma gbejade.ona ti aye fi wa fun fifi agbara gba sile ni nipa iwe ase lati owo awon alase idajo ti oniroyinba ti sesi ofin ti a la sile fun akoso ise akoroyin, tabi ti oniroyin ba ti se si abala ofin ti o la sile wipeoniroyin gbogbo se afihan awon nnkan fun igun ti oro naa kan. Ni iru asiko bayi, nigbati oba bo si pajawiri ati nigbati idasi awon alase eeto idajo ko ba se e gba, awon olopa to ndekuniwa odaran lee fi agbara gbese le awon atejade iroyin igbadegba, awon olopa gbodo fi iruigbesele naa to awon alase idajo leti ni kiakia eyim ti ko gbodo koja wakati merinlelogun tiigbesele waye. Ti awon alase idajo ko fowo si iru igbesele naa laarin wakati merinlelogun,awon olopa gbodo gbese kuro ohun ti won fi agbara gba nitori pe igbesele naa ti di aiba ofinmu. Ofin le gbe kale nipa bala gbogbo gbo wipe orisun awon ona ti owo ngba wole fun ileise iroyin igbadeigba gbodo di mimo.Ofin ko faye gba awon atejade iwe to ngbejade tabi se afihan awon nnkan to lodi si iwa rereawujo. Ofin ti se igbekale awon ona ti o ye lati dena awon ona Won le gba ru ofin naa.Atiku. 22A ko lee gba jije omo ilu, idiro labe ofin tabi oruko Lowo enikeni nitori oro oselu.Atiku. 23A gbodo fi enikeni sise tipapa tabi fun ijiya yato fun bi ofin se la a sile.Atiku. 24Enikeni le gbe igbese labe ofin lati dabobo Awon eto ati ohun to je tire labe ofin.Eto fun eni ti ape lejo lati so ti enu re ni asiko kasiko ninu igbejo wa laile yipada. Ipese wafun awon talaka nipaje awon ajo ti a gbe kale, fun iralowo lati pe ejo tabi lati jejo ti a bapewon lejo labe ile igbekale ati ibujoko gbogbo ile ejo. Ofin ni yoo so awon ohun ati ona tia fi lee san pada ti asise bawa nipa eeto Idajo.Atiku. 25A ko lee enikeni kuro niwaju Adajo ti ofin se eeto re sile. A ko gbodo fi iya je enikeni ayafilabe ofin gege bi a laa sile ninu Eyi ti o ti wa tele ki eniyan wuwa odaran naa. A ko gbodofi enikeni si aabo tipatipa fun ibolowo ewu aya fi lona ti ofin gba laa sile.Atiku. 26A le fi tipatipa gbe Omo ilu jade kuro ni Italy losi ilu abinibi re nipa ilana ti a la sile labeofin agbaye. A ko lee fi tipatipa gbe omo ilu lo si ilu Abinibi re nipa esun to je mo ti oselu.Atiku. 27Onikaluku lo ye ko jiya iwa odaran to ba wu.Eni ti afi esunodaran ko ti i jebi afi ti idajo to keyin ba waye. Ijiya ko gbodo je ohun ti o lodisi ona to bojumu lati huwa si omo eniyan, o si gbodo ni Erongba ati tun iwa odaran naa se.A ko fi aye gba idajo iku, ayafi bi ofin awon ologun se fi aye gba.

Hooray! Your file is uploaded and ready to be published.

Saved successfully!

Ooh no, something went wrong!