09.08.2015 Views

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

SHOW MORE
SHOW LESS

Create successful ePaper yourself

Turn your PDF publications into a flip-book with our unique Google optimized e-Paper software.

Atiku. 72Ofin kookan ti ile igbimo asofin ba yan ni awon igbi ile asofin yio yewolese lese funafowosi pelu idibo laarin awon igbimo naa. OgniEeto yi tun fi ye wa wipe ,a o se awon ofin ti o b a bo si pajawiri lesekese lai fi akoko sofoSiwa ju sii atiku yi tun so pe gbogbo a o se ayewo lekun rere nipa bi ofin naa se ri ati iruasiko ti a ofi idi ofin mule lati le je ki o ba aba ati imoran awon omo ile asofin mu,nitori idieyi a o fi aaye sile lati soro lekun rere lori re ,ni igba miran aaye wa fun idibo fun afowosiiru ofin naa,a si tun lee daa pada si ilasofin ti awon igbimo abi ioba ati ida marun ile asofinba beere fun ayewo ni ekun rere ,atiku yi si tun fi aaye sile fun ipolongo ise awon awonigbimo asofin.Igbese ti o to fun ayewo ati afowosi awon ofin gbodo je ilana ti o wa ninu ofin ti o je moofin idibo ati awon igbimo idibo ti o ba ilana adehun agbaaye mu,peluapapo iwe ayewoinawo.Atiku. 73Afowosi pelu abadofin awon ofin gbodo wa lati owo aare orileede laarin osu kan ti ofin naawaye.Ti awon ile ba si pa enu po pe o je pajawiri ofin naa gbodo waye ni asiko ti won ba panuposo lai fi asiko sofo tabi lai si aniani.A gbodo se ikede ofin yi j laarin ojo meedogun ti a ti se afowosi ofin yi ,tabi ni aarin asiko tio ye ki ofin naa waye.Atiku. 74Aree orileedede le beere leekan sii fun ayewo ni ekunrere nipa fifi to awon awon ile igbimoasofin l’eti ki o to fi owo si ofin yi ,ti awon igbmo ile asofin ba si tun panupo fi owo sii, o didandan ki aare fi owo si ki o si soo di ofin..Atiku. 75A ose ikede idibo lati se afagile die ninu ofin tabi afagile gbogbo re ,ti awon ara ilu babeere o kere ju won gbogbo je ogorun marun lona egberun(500'000)awon ti o ni eto funidibo abi marun(5) ile igbimo ijaba ipinle marun.A ko fi aye sile fun ibo lati fagile waon ofin ti ,ti o ba oro owo ori,iwe ayewo inawo,idarji atiitusile ninu oran,pelu adehun agbaaye ti o je mo awon nkan wonyi.Gbo gbo awon ti o ni eto idibo lati yan igbimo ile asofin ni o le kopa ninu iru idibo yiIru aba yi tio di ofin ti awon ti o dibi ba koja idaji awon awon ti o ni eto idibo,ti ayewo idiboti won se si je eyi ti o ba ilana ati ofin mu .Ofin wa ti o nse akoso iru idibo apapo yi. yi le waye ti o ba wa ti.Atiku. 76Ise sise gege asofin kogbo je eyi ti won fi ran ijoba pe ko ba won se ayafi ti ona ti won yoogbase se ise naa ati ohun ti won yoo se ti je lila sile ati pe o gbodo wa fun igba die ati funohun kan gbogiAtiku. 77Ijoba ko gbodo pase lati mun ofin se laije pe Awon ile Asofin ti fowo si iru ofin bee .

Hooray! Your file is uploaded and ready to be published.

Saved successfully!

Ooh no, something went wrong!