09.08.2015 Views

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

SHOW MORE
SHOW LESS

Create successful ePaper yourself

Turn your PDF publications into a flip-book with our unique Google optimized e-Paper software.

Ofin se ilana fun awon ona lati da abo bo ati Se igbelaruge fun ise owo.Atiku. 46Pelu erongba fun itesiwaju oro aje ati imudara eeto igbe aye gbadun awon osise ati niisedede pelu awon idi fun ipese, Orileede mo awon eto to je awon osise lati fowosowopo, niawon ona ati ninu gbedeke ti ofin gbekale nipa isakoso Awon okoowo.Atiku. 47Orileede olominira nse igbelaruge ati idabobo ifowopamo lorisrisi ona; ofin nfi iya jeni, onse idari Ati isakoso ona fun owo yiya.O nse igbelaruge awon ona fun awon lati yawo lati inu asuwon ifowopamo fun di oni ile,lati ko ile fun ra won ati fun ati idokowo ti ki i se taara nipa rira ipin idokowo ile ise nla towa ni orileede.AKOLE KARUNAWON ETO NIPA OSELUAtiku. 48Gbogbo omo ilu lokunrin ati lobinrin, ti won dagba tojubo, lo je oludibo. Ibo didi je ohun wafun eni kookan, ogbogba, olominira ati ni onibonkele.Ojuse idibo je ise si ilu. Ofin ti awon Asofin yoo se gbodo se idasile awon ohun to romo atiilana lab eyi ti awon ilu Italy to ngbe ni ile okeere yoo gba lati maa se ojuse won nipa ibodidi lasiko awon idibo, ati ona ti ibo naa yoo se wulo. Fun awon idi yi ‘Agbegbe idibookeere’ gbodo je dida sile, eyi ti won yoo fi ma dibo yan asoju si ile igbimo asofin mejeeji.Iye ijoko ti yoo wa gbodo je dida sile nipase iwe ofin eyi to gbodo ba ilana ti awon ileAsofin lasile nipase ofin sise. Eto lati dibo ko gbodo je eyi ti won koni gba eniyan laye latise ayafi fun ailera tabi gege bi ayorisi idajo fun odaran tabi nipase aikun ojuosuwon iwarere gege bi ofin se laa sile.Atiku. 49Gbogbo awon omo ilu loni eto ati ominira lati je omo egbe oselu ati lati se iranlowo nipaseeto Ijoba ar eni lati pinu awon eto isakoso ijoaba.Atiku. 50Gbogbo omo ilu lo leto lati lati ko iwe ehonu si ile igbimo asofin mejeeji lati bere fun ilananipa Tabi beere fun ohun ti awon eniyan nilo.Atiku. 51Gbogbo omo ilu yala okunrin tabi obinrin lo lee dije fun ipo oselu eyi won maa ndibo fun niogbogba asiko. Ofin lee fi aye gba awon omo ilu Italy ti ko gbe ni Italy lati ni eto kan naagege bi awon to ngbe lu lati aye fun idije ibo si ipo oselu ni orileede Enikeni ti a ba ranse pelati sise gege eniyan ti adibo yan si ipo oselu leto lati beere fun aye lati se awon ojuse tiwon yan si lai padanu ipo re ni ibi to ti nsise tele ki won to yan Sipo oselu.

Hooray! Your file is uploaded and ready to be published.

Saved successfully!

Ooh no, something went wrong!