09.08.2015 Views

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

SHOW MORE
SHOW LESS

Create successful ePaper yourself

Turn your PDF publications into a flip-book with our unique Google optimized e-Paper software.

awon imoran ijoba lati odo okan ninu ile Asofin tabi awon mejeeji ko tumo si pe won gbodokowe fi ipo sile.Aba wipe awon koni igbekele ninu ijoba ni idakan ninu mewa awon Asofin gbodo fowo si,won ko si lee jiroro lori re saaju ojo meta ti won gbe kaleAtiku. 95Olori igbimo lo nsakoso ohun si ni yoo maa dahun fun gbogbo awoon eeto ijoba.Olori igbimo ni yoo ri wipe awon eeto ijoba nipa oselu ati isakoso ijoba baramu, nipa gbigbelaruge ati mimojuto ise awon minisita.Gbogbo awon minisita ni won yoo jumo dahun fun ise igbimo minisita;sugbon olukulukuwon ni yoo dahun fun ile-ise ijoba ti won nsakoso.Ofin lo se igbekale isakoso ise olori igbimo, ati iye , ijafafa ati isakoso awon ile-ise ijoba.Atiku. 96Olori igbimo minisita ati awon minisita, koda leyin igbati won ba tiwon bati kowe fi ipowon sile, won lee la eeto idajo to wa fun esun odaran gege bi gbogbo eniyan koja fun iwaodaran ti won se nigbati won ba nsise gege ojuse won, niwon igbati ase ba ti wa lati odoawon Asofin Ajo Igbimo ati Awon Asofin Asoju,nipase asa ti ofin la sile.Abala kejiAtiku. 97Awon ipo ilu je tito lesese nipa igbekale ofin, la ti le e ripe eeto isakoso nlo dede laisiojusaju.Ilana to ipo ti se igbekale awon igun ijafafa, ojuse ati awon ohun ti owa ni ikawo osise.Igbani si ise ijoba ni o se e se nipa ifagagbaga idanwo, ayafi ni awon igba kan ti ofin gbekale.Atiku. 98Awon osise ijoba nsise fun orileede nikan.Ti won ba je omo ile igbimo Asofin, won le ma ni igbega lenu ise won, ayafi nipa biwon sesiwaju ara won wose.Ofin le fi gbedeke lele nipa eto ati je omo egbe oselu fun awon bii adajo majisirati, awonomo ologun to si wa lenu ise, awon agbofinro, ati asoju ijoba ni ile okeere.Abala ketaAwon Ajo OluranlowoAtiku. 99A nyan Igbimo ijoba apapo fun eeto Oro Aje ati Ise, gege bi ofin se la a sile, awon amoyeati asoju awon eka eeto oro aje, ni ona dogba ndogba ti yoo se afihan pataki bi won se potoati dangajia to.won duro bi igbimo ti awon ile Asofin ati Ijoba lee ma kan si nipa awon ojuseti ofin la sile fun won.

Hooray! Your file is uploaded and ready to be published.

Saved successfully!

Ooh no, something went wrong!