Atiku. 132Nipase ofin orileede, leyin igbati won ba ti fi oro lo awon igbimo Ekun,Idapo awon Ekun towa tele tabi dida sile awon Ekun titun ti won gbodo ni Milionu kan eniyan okere ju ti wonngbe nibe ni won le e se ipinu le lori, nigbati ibeere ba ti wa lati owo awon igbimo ilu ti wonnsoju idakan ninu meta awon eniyan ti oro naa kan, ti ibeere naa si ti je gbigba wole nipaseidibo eyi ti awon eniyan to po julo fowosi. Awon Agbegbe ati awon ilu ti won bere wipe kiwon ya awon kuro lara Ekun kan kiwon si da awon po di Ekun miran ni won le gba laye latise bee, nipa titele idibo ate ofin orileede olominira, eyi ti awon olugbe to pojulo awonagbegbe tabi agbegbe, awon Ilu tabi ilu ti oro naa kan dibo fun, ati leyin igba ti won ba tigbo oro Igbimo Ekun.Atiku. 133Iyipada aala Agbegbe ati gbigbekale Agbegbe titun laarin Ekun ni ofin Orileede olomira nseakoso, nipase ogbo atinuwa awon Ilu, leyin ti won ba ti fi oro naa lo ekun.Ekun naa, leyin ti won ba ti fi oro na to awon eniyan ti oro kan leti, ni won le dasile nipaseawon ofin tire awon Ilu titun laarin ile tire, ti won yoo si se atunse awon sakani ati orukowonAKOLE KEFAAWON OHUN TI OFIN ORILEEDE FI AYE GBAAbala KinniIle Ejo to wa fun Ofin orileedeAtiku. 134Ile-ejo Ofin ti orileede gbodo gbe idajo kale lori: edeaiyede nipa boya awon ofin ti ipinle atiEkun gbe kale ba ofin orileede mu; ija to ba waye lori pipin awon agbara ipinle ati awonagbara ti won pin fun ipinle ati awon Ekun,ati laarin awon Ekun; esun ti won ba fi kan Aareorilede olomira ati awon minisita, nipase awon igbekale ofin orileede.Atiku. 135Ile-ejo ofin ti orileede gbodo ni Adajo meedogun.Idakan ninu meta ni Aare orileede olomirayoo yan, idakan ninu meta ni Ile Asofin mejeeji ninu ipade asepo won yoo yan ati idakan toku ni Ile-ejo to gaju sanponna to wa fun isakoso yoo yan.Awon Adajo Ile-ejo ofin orileede ni won gbodo yan laarin awon adajo, pelu awon Adajo to tifeyinti, ti wo wa lati ile-ejo giga saponna towa fun isakoso, laarin awon Ojogbo to je olukoimo ofin lekunrere ni Yunifasiti ati awon agbejoro ti won ti ngbejoro fun ogun odun o keretan.Awon Adajo Ile-ejo to wa fun ofin orileede ni won maa nyan sipo fun odun mesan, bere latiojo ti won ba ti bura fun won, ati pe won ko le e tun won yan leekeji.Leyin opin saa won,awon adajo ile-ejo ofin orileede ni won yoo fi ipo ati awon ojuse won sile.Ile-ejo naa yoo yan Olori laarin awon Adajo, ni pase bi ilana ti ofin la sile, ti yoo wa nipofun odun meta ti won si tun le tun yan, nipa ibowofun ni gbogbo ona igba ti saa awon adajoIle-ejon ofin yoo wa sopin.Ipo adajo ile-ejo ofin ko see dimu papo mo ipo miran bii omo ileigbimo Asofin, omo igbimo Agbegbe, ise agbejoro ati pelu ipo miran ti ofin la sile. Ni asiko
iyokuro nipo Aare orileede olominira, yato si awon Adajo ile-ejo ofin, eniyan merindinlogunni won yoo yan nipa eyi-je-eyi-o-je laarin awon omo ilu ti won kun oju osunwonlati dije gege bi Omo ile Asofin Ajo igbimo, eyi ti ile Assofin maa nse eeto re ni odun mesanmesan nipa idibo gege bi won se ma ntele lati yan awon Adajo sanponna.Atiku. 136Nigbati ile-ejo ba kede wipe ofin kan tabi ilkana ofin to ni agbara ofin ko ba ofin orileedemu, idaduro yoo ba imulo iru ofin be lati ojo keji ti won ba ti te ipinnu naa jade. Ipinnu ileejogbodo je tite jade ti won yoo soi fi to awon ile Asofin ati Igbimo Agbegbe ti oro naa kan,ki woon lee tele ilana ti ofin la sile nigba kuugba ti o ba ye.Atiku. 137Ofin orileede gbodo se igbekale awon ilana, ati ona fun gbigbe awon idajo kale lori bibaofin mu, ati idaloju ominira fun awon Adajo fun ofin orileede. Awon Ofin sanponna ni yoose igbekale awon ilana yoku to se pataki fun ofin orileede ati imuse se ile-ejo naa. Won ko fiaye gba pipe ejo kotemilorun lori ipinnu ile-ejo ofin orileede.Abala KejiAtunse si ofin orileedea ati awon Ofin miran fun OrileedeAtiku. 138Awon ofin fun atunse ofin orileede ati awon ofin orileede miran ni Awon ile Asofin mejeejigbodo gba wole leyin ijiroro meji to tele ara won pelu alafo ti din ni osu meta, eyi ti awonomo ile asofin topo julo ni ile kookan gbodo dibo fun ninu idibo won eekeji. Iru awon ofinbee ni won gbodo gbe kale siwaju gbogbo eniyan fun idibo si, laarin osu meta si igba ti wonte won jade, iru ibeere be ni idakan ninu marun awon omo ile Asofin gbodo beere fun tabiegberun lona eedegbeta oludibo tabi Igbimo Ekun marun. Ofin ti won gbe kale fun idibo siko gbodo je kikede ti awon oludibo topoju ko ba dibo fowo si.Idibo gbogbo gbo ko gbodo waye mo ti Idameji ninu meta awon ile asofin bati dibo fowosiiru ofin bee.Atiku. 139Bi orileede olominira ti ri kogbodo je ohun ti won yoo se atunse ofin si.