09.08.2015 Views

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

SHOW MORE
SHOW LESS

You also want an ePaper? Increase the reach of your titles

YUMPU automatically turns print PDFs into web optimized ePapers that Google loves.

Awon omo igbomo yi maa nwa ni ipo fun odun merin, won ko si le dibo fun leekeji ni kiakiati odun meri akoko ba pari. Ni asiko tiwon ba wa ni ipo yi, won le ma fi oruko sile gegeakosemose tabi ki won je omo ile asofin tabi omo igbimo ijoba agbegbe.Atiku. 105Igbimo giga to wa fun eeto Idajo, gegebi bi ilasile ti eka eeto idajo gbe kale, ni agbara ati aselati gba eniyan sise, gbe ise funni, gbelo si ibomiran, se igbega ati lati fi iya je awon Adajo.Atiku. 106Won maa nyan Adajo nipa Idawon oni ifiga gbaga. Ofin to wa fun isakoso eeto idajo fi aayegba yiyan sipo nipa idibo awon Adajo ti afi ipo dalola ti won le maa se ojuse won gege adajoto maa njoko ni Oun nikan.Nipa ti tele aba to wa lati odo igbimo giga fun eeto idajo,won lee yan awon Ojogbon to nseoluko ni Yunifasiti lekunrere ati awon Agbejoro ti won won ti to Odun meedogun lenu ise tiwon s fi oruko sile ni Ile Ejo Giga be Akosemose pataki to ti se ise to wuni lori gege bioludajo ile ejo kotemilorun.Atiku. 107A ko lee yo awon Adajo kuro nipo; ako lee yo won nipo tabi ki a da won duro tabi ki a gbewon lo si ile ejo miran tabi fun ojuse miran ayafi nipa ipinu Igbimo giga to fun eeto Idajo,iru ipinu bee gbodo sele yala fun awon idi ti ilana ati daabo bo ara eni ti eeto idajo la siletabi pelu ifowosi awon Adajo ti oro naa kan.Minisita to wa fun eeto Idajo le bere igbese ifiyajeni.Iyato to wa laarin awon Adajo ni nipa ojuse otooto ti won nse. Awon Olupejo fun ijoba njeanfani ti ofin laa sile eyi to gbe won lese nipa ilana to jemo isakoso eeto idajo.Atiku. 108Awon ilana to jemo isakoso eeto Idajo ati awon Adajo ni ofin la sile.Ofin se idaniloju pe Ominira wa fun awon Adajo Ile Ejo Pataki,awon olupejo Ijoba, ati fungbog o eniyan to nkopa nibi isakoso idajo.Atiku. 109Awon alase eeto nipa ofin ni eto tara lati lo awon Olopa to wa fun idajo.Atiku. 110<strong>La</strong>ise afojudi si ase Igbimo giga to wa eeto Idajo,Minisita fun eeto Idajo ni ojuse lati seakoso ati lati ripe awon ise to je mo eeto idajo nlo daradara.Abala kejiAtiku. 111Agbara ati ase lati gbo ejo ni a nmulo nipase bi ofin se laa sile. Gbogbo ejo to ti a nse ni IleEjo ni o gbodo je nipa eeto Gbigbo otun ati osi ati pe awon igun mejeeji ti eto si ilana kannaa niwaju adajo ti kogbodo se ojusaju to je igun keta.

Hooray! Your file is uploaded and ready to be published.

Saved successfully!

Ooh no, something went wrong!