09.08.2015 Views

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

SHOW MORE
SHOW LESS

You also want an ePaper? Increase the reach of your titles

YUMPU automatically turns print PDFs into web optimized ePapers that Google loves.

Idibo lati yan Aare orileede olominira gbodo je nipa idibo bonkele ti idameji ninu metaawon asofin gbodo dibo yan.Leyin idibo emeta, idbo won asoju to poju ni yoo je lilo.Atiku. 84Omo ilu to ba ti to omo aadota odun to si njegbadun awon eto nipa oselu ati gege bi omo iluni won lee dibo fun gege bi Aare.Ipo Aare orileede olominira ko nsee dimu pelu ipo miran.Eeto fun owo gbamabinu ati ajo fun itoju Aare ni ofin gbekale.Atiku. 85Aare orileede olominira ni won ndibo yan fun odun MejeTo ba ku Ogbon ojo ki saa Aare tan, Aare Ile Asofin Asoju yoo pe ipade asepo awon ileAsofin mejeeji ati awon asoju ti won dibo yan lati agbegbe lati yan Aare titun fun orileedeolominira.Ti awon ile Asofin ba wa ni tituka tabi ti ko ba to osu meta fun mo ti won yoo tu ile ka, idiboyan Aare titun yoo waye laarin ojo meedogun ti awon ile Asofin titun ba pade.Ni iru asikobayi, agbara Aare to wa lori oye yoo di sisun siwaju.Atiku. 86Awon ojuse ti Aare orileede, ni gbogbo igba ti Aare ko ba le se awon ojuse naa, Aare ileAsofin Ajo Igbimo ni yoo maa se ojuse naa.Ni asiko ti Aare ba je alailagbra to wa lailai tabi iku tabi ikowe fipo sile Aare orieede, Aareile Igbimo Asoju yoo pe fun idibo aare titun laarin ojo meedogun, ayafi ni asiko to ba gun sieyi ti o le sele nigbati awon ile Asofin ba wa ni tituka tabi ti ko ba to osu meta mo ti wonyoo tu won ka.Atiku. 87Aare orileede olominira ni olori orileede, Oun si ni o duro fun Isokan Orileede.Aare lee fi ranse si Awon Ile Igbimo asofin. Aare lo maa npe fun idibo si awon ile Asofintitun, Oun lo si maa npe ipade won akoko.Aare Gbodo maa:Fi ase si fifi abadofin ti ijoba ranse si awon ile Asofin.Se ikede ofin, gbe awon ase ti o ni agbara ofin jade bee gege awon ilana.Pe fun awon idibo ni awon asiko ti ofin la sileYan awon osise fun ijoba gege bi ofin se laa sile.Gba awon asoju orileede miran wole, fowosi awon adehun to wa laarin won ati awonorileede miran eyi tiawon Ile asofin ti fasesi nibi ti o ba tiye.Aare ni alase ati oludari awon omo ogun ti orileede, Oun si lo maa dari ipade Igbimo togajulo to wa fun aabo eyi ofin da sile, oun lo se le se ikede ogun leyin ti awon ile Asofin bati fowosi.Aare gbodo je oludari ipade igbimo idajo.Aare lee dariji Arufin tabi ki o din ijiya kuAare lo lee fi amin eye ifidanilola ti orileede fun awon eniyan.

Hooray! Your file is uploaded and ready to be published.

Saved successfully!

Ooh no, something went wrong!