09.08.2015 Views

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

La Costituzione della Repubblica Italiana

SHOW MORE
SHOW LESS

Create successful ePaper yourself

Turn your PDF publications into a flip-book with our unique Google optimized e-Paper software.

Awon ekun Trentino-Alto Adige/sudtirol ni awon agbegbe Trent ati Bolzano ti won da durolabe won.Awon aaye ati ipese pataki fun idaduro, eyi to je mo awon nnkan ti o wa ni abe Atiku117(ese ketadinlogofa) , igbese keji ati igbese kete labe leta L eyi ti so nipa awon ohun o gbodowa fun isakoso ti awon Adajo Alafia ati labe leta N ati leta S, awon eyi ni ofin ipinle le funawon Ekun yoku, nipase nipa ibeere Ekun ti oro yi kan leyin ti won ba ti kan si awon alaseibile, nipa titele aown ilana to wa Atiku 119 (ese kokandinlogota). Awon Ile asofin mejeejigbodo fowo si ofin naa pelu omo egbe to poju lo, nipase awon adehun to wa larin Ipinle atiEkun ti oro naa kan.Atiku. 117Agbara Isofin wa fun Ipinle ati Ekun ni pa titele ofin orileede lati nipa awon idalekun ti a mujade lati abe ofin EU ati awon ojuse si awon orileede miran.Ipinle nika loni agbara isofin nipa awon ohun to wa ni isale wonyin:a)Eeto Isakoso fun ile okeere ati ajosepo pelu awon Orileede miran; ajosepo larin ipinle atiAjo Ile Europe; eto lati dabobo awon to nse atipo ati iduro labe ofin awon ti kii se omoEurope.b) Wiwole ati Jijade ni Ilu.c)Ibasepo laarin Orileede olominira ati awon Egbe to wa fun Esind)Aabo ati Awon ologun,Idabobo Ilu;Imura ogun;Ohun ija ogun ati eyi to maa nbu gbamu;e)owo orileede, eeto ifowopamo ati oja fun inawo;idabobo ifigagbaga; eeto pasiaparo owo siile okeere;eeto owo ori ati isiro owo;Jije deede awon orisun iwole owo;f)Awon ajo ipinle ati awon eto idibo, eeto idibo fun eto ilu;Idibo si ile asofin ajo Europe;g)Isakoso nipa ofin ti ipinle ati awon ajo ijaba;h)Jijoba alafia ati aabo,yato si isakoso awon olopa ibile;i)Jije Omo ilu, iduro lawujo ati ibujoko iforukosile;l)Agbara ati Ase lti gbo ejo; Ofin esun odaran ati eyi tii ki se ti odaran, isakoso fun eetoidajo;m)Sise gbedeke awon anfani to kere julo to jemo ti ara ilu ati igbayagbadun eyi yoo wa fungbogbo eniyan to wa ni ilu;n)Ipese gbogbo gbo fun eeto eko;o)Eeto abo fun igbayegbadun;p)Ofin fun idibo,awon ajo isakoso ati ojuse tose koko awon ilu, agbegbe ati awon ilu nla;q) Asa,idabobo awon ala ilu ati ki aisan ma wole lati awon orileede miranr) iwo ati wiwon, odiwon asiko,ikojopo ati fifi imo ero computer se akoso awon ohun imo toje ti ilu, isakoso agbegbe ati ijoba ibile; ise awon amoye;s)Idabobo ayika, awon eranko ati eweko ati awon ohun isembaye.Sise ofin to ba ti Orileede olominira mu lori awon nnkan wonyi:Ibasepo pelu awon orileede miran ati awon orileede ajo Europe;Lori isowo pelu awon orileede miran;Bibi lowo ewu ati aabo fun ise;Eeto eko, eyi dalori idaduro awon ile eko giga yato fun eeto eko fun ise-owo kiko atiikosemose;Eeto Iwadi imo ijinle ati ise ero pelu atileyin imu ohun titun jade fun igun to nse ipese;

Hooray! Your file is uploaded and ready to be published.

Saved successfully!

Ooh no, something went wrong!