12.11.2014 Views

o_196h0fp7b15b9sam1rr8a4j13d8a.pdf

You also want an ePaper? Increase the reach of your titles

YUMPU automatically turns print PDFs into web optimized ePapers that Google loves.

174 Unit 12: Pípàdé ènìyàn ní ibùdó ò. kò. -òfurufú ní Èkó

5 ibùdó o≥koΩ$-òfurufú

airport

6 sún kõõrõ fà kõõrõ traffic jam

7 àwo≥n adigunjalè armed robbers

8 gúnlõΩ to arrive or land

9 ilé-ìtura hotel

10 ànæfàní opportunity

Listening or reading comprehension

(CD 2; 22)

Listen to or read the following passage and then answer the questions

that follow.

Ìrìnàjò lo≥sí ìlú Loœ$n;doΩ$nù

Ní oßù tí ó ko≥já, Túnjí lo≥sí ìlú Loœ$n;doΩ$nù. Ó jáde láti loœ$ gbé õrù rõΩni ó

pàdé oΩ$rõœ rõΩláti ilé-õΩkoœ$ oníwèémõœwàá ní Ìbàdàn. Orúko≥oΩ$rõœ rõΩyìí ni

Toœ$põœ. Inú Túnjí dùn púpoΩ$ láti rí oΩ$rõœ rõΩyìí, ó sì bí i pé kí ní ó n;ße ní

ìlú Loœ $n;doΩ $nù. Toœ $põœ so≥fún un pé òun kúrò ní ìlú nàìjíríyà nítorí gbogbo

rògbòdìyàn k’á ßí ilé-ìwé lónìí, k’á tún tì í loœ$la. Ó so≥pé lõœhìn tí òun fi

o≥dún mõœta ßòfò ní Yunifásitì ti O˘lábísí ní Àgoœ $-Ìwòyè, tí òun kò sì kúrò

ní kíáàsì kan náà, màmá àti bàbá òun rán òun wá ìlu Loœ$n;doΩ$nù kí òun

lè parí õΩkoœ$ òun lásìkò.

YàtoΩ$ sí rògbòdìyàn ilé-õΩkoœ$ gíga nígbà gbogbo, Toœ$põœ so≥pé wàhálà

àwo≥n adigunjalè põΩlú nn;kan tí ó jõœ kí gbígbé ní ìlú Nàìjíríyà sú òun.

O¸˘sán o≥joœ$ kan ni àwo≥n olè wo≥ilé àwo≥n Toœ$põœ ní Èkó. Lõœhìn tí woœ$n dõœrù

ikú bà woœ$n, woœ$n so≥pé kí gbogbo wo≥n doΩ$bálõΩkí woœ$n sí di ojú wo≥n.

O¸˘kan nínú àwo≥n olè yìí n;ßoœ$ Toœ$põœ àti àwo≥n õbí rõΩlórí ìdoΩ$bálõΩpõΩlú

ìbo≥n. Àwo≥n olè mõœta yòókú n;wá nnækan tí woΩ$n máa kó jáde láti yàrá

kan sí èkejì. Nígbà tí woœ$n máa fi kúrò ní ilé àwo≥n Toœ$põœ, woœ$n ti gbé

koΩ$næpútà, õΩro≥amóhùn máwòrán, rédíò, àti owó rõpõtõ.

Lõœhin ìßõΩlõΩyìí, ìlú Nàìjíríyà sú Toœ$põœ ó sì dágbére fún ìlú Nàìjíríyà

pé ó dìgbóße. Toœ$põœ kò ì tí ì padà sí ìlú Nàìjíríyà láti ìgbà yìí.

Questions

1 What are the two main reasons why Tope left Nigeria?

2 How did Tunji happen to know Tope?

3 What did the armed robbers steal at Tope’s house?

4 How many years did Tope spend at university in Nigeria before

he decided to leave for London?

Hooray! Your file is uploaded and ready to be published.

Saved successfully!

Ooh no, something went wrong!