12.11.2014 Views

o_196h0fp7b15b9sam1rr8a4j13d8a.pdf

Create successful ePaper yourself

Turn your PDF publications into a flip-book with our unique Google optimized e-Paper software.

Unit 13: Visiting different places 185

1111

2

3

4

5

6

7

8

9

10

1111

12

13

14

15

16

17

18

19

20

21

22

23

24

25

26

27

28

29

30

31

32

33

34

35

36

37

38

39

40

41

4222

Listening or reading comprehension

(CD 2; 28)

Listen to or read the following letter and then answer the questions

that follow.

265 Lafayette

Hempstead, Long Island

NY 11798

8/31/04

Túnjí àti õΩgboœ$n mi oΩ$woœ$n,

Inú mi dùn láti ko≥ìwé yìí sí yín. AyoΩ$ àti àlàáfíà ni

mo fi padà sí ìlú New York. Mo n;koΩ$wé yìí láti dúpõœ

loœ$woœ$ õΩyin méjèèjì fún gbogbo aájò mi tí õ ße nígbà tí mo

wá sí ìlú Nàìjíríyà. Mo dúpõœ fún gbogbo ibi tí õ mú mi lo≥

bí i ìko≥gòsì, Òkè Olúmo≥ní ìlú Abõœòkúta, ààfin OŏΩ$ni ti

IfõΩ, etí òkun ní Èkó, Lõœkí, Ibùdó oko õrú ni Badagry àti

bõœõΩbõœõΩlo≥.

Inú mi dùn láti rí oríßiríßi ìlú àti gbogbo ibi tí õ mú

mi lo≥. Nísisìyí mo lè so≥pé mo mo≥ilõΩYorùbá nítòótoœ$.

Mo koœ$ o≥gboœ$n púpoΩ$ loœ$doΩ$ oΩ$poΩ$lo≥poΩ

$ ènìyàn tí mo bá pàdé.

Mo koœ$ õΩkoœ$ pàtàkì nípa rírin ìrìnàjò. Bí àwo≥n ènìyàn bá

n;so≥pé orílõΩèdè Áfíríkà kúsõΩõœ mo mo≥nísisìyí pé bí ìßõœ ße

wa ní Áfíríkà bõœõΩnáà ni o≥roΩ$ oríßiríßi náà wà níbõΩ. Mo

mo≥nísisìyí pé a kò lè máa soΩ$roΩ$ Áfíríkà bí õni pé a n;soΩ$roΩ

ìlú kan ßoßo.

YàtoΩ$ sí Yorùbá tí mo koœ$ fún oßù mõœta tí mo lò ní

ìlú Nàìjíríà, mo tún gboœ$ àwo≥n ti woœ$n n;so≥oríßiríßi èdè.

Bí èdè ße poΩ$ ní ìlú Nàìjíríyà náà ni àßà oríßiríßi náà poΩ

níbõΩ.

Àdúrà mi ni pé kí O˘loœ$run fún mi ní ànæfààní láti

padà wá sí ìlú Nàìjíríyà. Màmá àti bàbá mi kí yín. Õ bá

mi kí àwo≥n òbí Túnjí àti gbogbo àwo≥n oΩ$rõœ yín tí mo bá

pàdé ní Nàìjíríyà. Ó dìgbà kan ná.

Èmi ni tiyín nítòótoœ$

Carla

Hooray! Your file is uploaded and ready to be published.

Saved successfully!

Ooh no, something went wrong!