12.11.2014 Views

o_196h0fp7b15b9sam1rr8a4j13d8a.pdf

Create successful ePaper yourself

Turn your PDF publications into a flip-book with our unique Google optimized e-Paper software.

208 Unit 15: Ṣíṣe ìwádìí nípa ènìyàn

BÚNMI: Kí l’ó dé?

DOYIN: Nítorí pé gbogbo fíìmù wo≥n tí mo ti rí ni woœ$n n;lo ògidì

Yorùbá, láìsí èdè Òyìnbó rárá. Mo korìíra àwo≥n fíìmù

Yorùbá t’ó jõœ pé ààboΩ$ Yorùbá àti ààboΩ$ èdè Òyìnbó ni

woœ$n máa n;so≥.

BÚNMI: Kò burú, bí o kò bá fõœ rí fíìmù kankan, kí ni nnækan

mìíràn tí ó fõœ kà ße?

DOYIN: Jõœ k’á lo≥sí ibi àsè Dúpõœ. Òjó Õtì tí ó n;boœ$ ni o≥joœ$ ìbí rõΩ,

ó sì so≥fún mi pé òun fõœ ße àsè lálõœ o≥joœ$ yìí.

BÚNMI: Íé o moΩ$ pé mi o fõœràn láti jó. Mi ò sì fõœràn ariwo. Íé a

lè lo≥sí ilé oúnjõ àwo≥n Íainíìsì tí ó wà ní títì lkòròdú. Íé

o moΩ$ pé mo fõœràn oúnjõ àwo≥n Íainíìsì.

DOYIN: Kò burù. Èmi náà fõœràn oúnjõ àwo≥n Íainíìsì. Màá wá

gbé õ nílé õ loœ$joœ$ Õtì tí ó n;boΩ$ ní agogo mõœfà ìroΩ$lõœ.

BÚNMI: Kò burú. Ó dàboΩ$.

Questions

1 Why is it that neither Bunmi nor Doyin could watch any of

Professor Iṣọla’s films?

2 What did Doyin and Bunmi do together at last?

3 Whose party did Doyin want them to attend?

Hooray! Your file is uploaded and ready to be published.

Saved successfully!

Ooh no, something went wrong!